Michael Aondoaka
Ìrísí
Michael Aondoaka jẹ́ agbẹjọ́ro àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọdún 2007 Títí di 2010.[1]. Ó jẹ́ ọmọ bíbí ilé Benue, tí àbí ni ọdún 1962.[2].
Ẹgbẹ Legal Practitioners Privileges Committee ti orílẹ-èdè Nàìjíría gba ipò Senior advocate of Nigeria (SAN) lówó Aondoakaa ni 2010.[3]