Michael Baah
Ìrísí
Michael Opoku Baah jẹ elere badminton orilẹ ede Ghana ti a bini ọjọ keji lèèlogun, óṣu July, ọdun 1996[1][2][3].
Igbèsi Àyè ati Àṣèyọri Àràkunrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Michael wa lati Takordia ni órilẹ ede Ghana to si jẹ Akẹẹkọ ti ile iwe giga, Cape Coast[4][5]. Ni óṣu february, ọdun 2018 Michael ati Akẹgbẹ rẹ Abraham Ayittey, Emmanuel Yaw Donkor ati Daniel Sam gba idẹ ninu idije team ti Thomas ati Uber[6][7][8]. Ni óṣu April, Ọdun 2019 elere naa kopa ninu ere ilẹ Afirica to waye ni ilu Port Harcout ni ilẹ Naigiria[9][10].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.flashscore.com/player/opoku-baah-michael/jiaGnRkm/
- ↑ https://mobile.ghanaweb.com/GhanaHomePage/SportsArchive/Team-Ghana-targets-medal-zone-in-badminton-at-Commonwealth-Games-636537
- ↑ https://bwfbadminton.com/player/64194/michael-opoku-baah
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-07. Retrieved 2023-03-10.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-01. Retrieved 2023-03-10.
- ↑ http://ghheadlines.com/agency/ghana-news-agency/20190722/129196993/india-dominates-again-at-2019-j-e-wilson-badminton-tournament
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-01. Retrieved 2023-03-10.
- ↑ https://citinewsroom.com/2018/03/lets-make-history-at-the-commonwealth-games-abraham-aryettey/
- ↑ https://www.modernghana.com/sports/925608/badminton-association-of-ghana-prepare-for-african-games-qua.html
- ↑ https://mobile.ghanaweb.com/GhanaHomePage/SportsArchive/National-badminton-team-in-a-flying-start-at-Africa-Championship-740847