Jump to content

Michael Bloomberg

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Michael Bloomberg
108th Alákòóso Ìlú-ńlá New York
In office
January 1, 2002 – December 31, 2013
DeputyPatricia Harris
AsíwájúRudy Giuliani
Arọ́pòBill de Blasio
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Michael Rubens Bloomberg

14 Oṣù Kejì 1942 (1942-02-14) (ọmọ ọdún 82)
Boston, Massachusetts, U.S.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic (kí ó tó di 2001, 2018–títí di àkókò yìí)
Other political
affiliations
Independent (2007–2018)
Republican (2001–2007)
(Àwọn) olólùfẹ́
Susan Brown-Meyer
(m. 1975; div. 1993)
Domestic partnerDiana Taylor (2000–àkókò yìí
Àwọn ọmọ2, including Georgina
EducationJohns Hopkins University (BS)
Harvard University (MBA)
Net worthUS$61.8 billion (February 2020)[1]
Signature
WebsiteOfficial website

Michael Rubens Bloomberg[2] tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1942 (February 14, 1942) jẹ́ pàràkòyí olóṣèlú, oníṣòwò àti oǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Òun ni Aláṣẹ àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ Bloomberg L.P., Bloomberg ni Alákòóso Ìlú-ńlá New York láti ọdún 2002 sí 2013. Lọ́wọ́ báyìí, òun ní adíje dùpò Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Democratic Party tí yóò wáyé lọ́dún 2020.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Michael Bloomberg". Forbes. https://www.forbes.com/profile/michael-bloomberg. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :7
  3. Burns, Alexander (November 24, 2019). "Michael Bloomberg Joins 2020 Democratic Field for President". New York Times. https://www.nytimes.com/2019/11/24/us/politics/michael-bloomberg-2020-presidency.html.