Midé Fúnmi Martins
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Mide Funmi Martins)
Midé Fúnmi Martins (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1979) jẹ́ Òṣeré-bìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ gbajúgbajà òṣèré-bìnrin olóògbé Fúnmi Martins tó ṣaláìsí lọ́dún 2002. Midé Martins darapọ̀ mọ́ àwọn Òṣeré sinimá àgbéléwò ní kété tí ìyá rẹ di olóògbé. Ó fẹ́ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò tí a mọ sí Afeez Owó.[1] Ọmọ méjì ni ó bí .[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Friends gave my wife wrong advice to ruin our marriage –Afeez Owo". Punch Newspapers. 2015-12-15. Retrieved 2019-10-05.
- ↑ "Mide Martins Bio, Age, Father, Husband Age, Instagram, Movies And More". Informationcradle. 2017-07-25. Archived from the original on 2019-03-23. Retrieved 2019-10-05.