Mimi Belete
Ìrísí
Mimi Belete (right) in 2015 | ||||||||||||||||
Òrọ̀ ẹni | ||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 9 June 1988 Ethiopia | (ọmọ ọdún 36)|||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Mimi Belete Gebregeiorges ni a bini ọjọ kẹsan, óṣu June, ọdun 1988 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ede Ethiopia to da lori ere sisa ti arin ati ọna jinjin. Arabinrin naa gba órukọ metres ti ẹgbẹrun marun ninu ere ilẹ Asia ti ọdun 2010[1][2].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 2009, Mimi yege ninu idije ti Eurocross. Ni ọdun 2009, Mimi kopa ninu Idije Agbaye lori ere sisa[3]. Ni ọdun 2010, Mimi ṣoju fun ẹgbẹ Asia-Pacific ninu Cup Continental ti IAAF nibi to ti gbe ipo kẹrin. Ni ọdun 2010, Belete gba ami ẹyẹ ti ọla fun ere ilẹ Asia ni óṣu November[3]. Ni ọjọ kèjila, óṣu October, ọdun 2018, Mimi kopa ninu Marathon ti Toronto pẹlu wakati 2:22:28[4].