Jump to content

Mo'Cheddah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mocheddahni ndaniTv

Modupe-oreoluwa Oyeyemi Ola ti abi ni ojo kerindinlogun osu kewaa, odun 1990 ti oruko ori itage re si n je Mo'Cheddah (nigba miran ti a le pe ni Mocheeda tabi Mocheddah), ti o je okorin ati Rapper ti orile ede naijiria. o se ifilole studio debut album re ti o pe ni Franchise Celebrity ni odun 2010 nigba ti o wa pelu knighthouse Entertainment. awo ti o fi lole ni 2009 ti o je promotional single re ti o pe ni "if you want me". o kuro ni knighthouse ni osu keji odun 2012, leytin igba naa ni o da ile ise orin re sile ti o pe ni Cheddah Music.

Mo cheddah je omo ti abi ni ojo kerindinlogun osu kewaa ni odun 1990, ni ipinle Eko. o je omo kerin ninu omo marunun ti awon obi re bi, ti a si le to pinpin re losi ipinle osun, eyi ti o je ilu awon obi re.

o pari eko alako bere re ni University of lagos Staff School ni Àdàkọ:Yaba, Ilu Àdàkọ:Eko, o si lo si Lady Of Apostles, Àdàkọ:Yaba nibi ti o ti pari eto eko girama re. o je akekoo gboye ni ise Creative Art lati Fasiti ti Ilu eko, Àdàkọ:UNILAG.

Mo cheddah nigba ti o wa ni omo odun meji ni o bere sini fi creative side e han. ni ibere, o ni fe si ki a sere oritage, sugbon nigbeyin o bo si ori Orin kiko. o wa lara awon okorin ti ile ise knighthouse. leyin ti o kuro ni knighthouse ni o da ile ise orin ti re sile, ti o si pe ni MOCHEDDAH MUSIC. leyin ti o da ile ise naa sile ni o bere sini sise lori Awo orin elekeji ti o si ye ki o gbe jade ni odun 2016. yato si ki a ko roin, Mo cheddah ni imo lori bi ati se n ran Aso, ti a moi si.

Studio albums
  • Franchise Celebrity (2010)
Selected singles
  • "Survive"
  • "My Time"
  • "Destinambari (featuring Phyno)
  • "Tori Olorun"
  • "Bad"
  • "Coming for You" (featuring May D)
Year Event Prize Recipient Result
2010 MTV Africa Music Awards 2010 Best New Artist Gbàá
Channel O Music Video Awards Best Female Video "If You Want Me"

(featuring Othello)

Gbàá
2011 The Headies Hip Hop World Revelation of the Year style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
2014 ELOY Awards[1] style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | N/A|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé

This list is incomplete; you can help by adding missing items. (February 2016

Year Title Director Ref
2015 Bad clarence peters [2]

ni osu karun, odun 2018, o se igbeyawo pelu ololufe re ti o ti pe, Omooba Bukunyi Olateru-Olagbegi ni aye kan ni ipinle Eko ni Orile Ede Naijiria[3] . Gege bi aya omooba, o ni eto lati lo ati lati fi Olori' si iwaju oruko re nigba ti won ba fe pe.

  1. "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 20 October 2014. 
  2. "Mo'Cheddah Singer breathes chic new life into 'Bad' with Olamide [Video]". Pulse.com.gh. David Mawuli. Archived from the original on 12 March 2016. Retrieved 23 February 2016. 
  3. Agbo, Njideka (30 May 2018). "Mocheddah Gets Married To Longtime Boyfriend Bukunyi Olateru-Olagbegi". The Guardian Newspaper (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 19 October 2018. https://web.archive.org/web/20181019005953/http://guardian.ng/life/mocheddah-gets-married-to-longtime-boyfriend-bukunyi-olateru-olagbegi/. Retrieved 17 October 2018.