Monalisa Chinda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search


Monalisa Chinda
Ọjọ́ìbíMonalisa Chinda
13 Oṣù Kẹ̀sán 1974 (1974-09-13) (ọmọ ọdún 46)
Port Harcourt, Nigeria
Orílẹ̀-èdèỌmọ Nàìjíríà
Iṣẹ́Òṣèrébìnrin, olóòtú sinimá àgbéléwò, olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́
Ìgbà iṣẹ́ọdún 1996 títí di àkókò yìí

Monalisa Chinda tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1974 (13th September 1974)[1] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ olóòtú ètò orí tẹlifíṣàn àti gbajúmọ̀ olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Monalisa Chinda’s 40th Birthday Celebration". bellanaija.com. Retrieved 22 October 2014. 
  2. "'Mona Lisa Chinda' That is not the real me". Retrieved 4 May 2014.