Morenike Olasumbo Obadina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Morẹ́nikéjì Ọlásùḿbọ̀ Ọbádínà (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kẹwàá ọdún 1963) jẹ́ adájọ́ ilé-ẹjọ́ gíga ìjọba-Ìpínlẹ̀ Èkó tí ó wà ní Igbóṣeré ní Nigeria.[1][2]. Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó yàn án gẹ́gẹ́ bí adájọ́ lọ́dún 2001

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ayobami-Ojo, Yetunde (2015-07-16). "Woman gets N10 million award for defamation". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2023-03-12. 
  2. Eribake, Akintayo (2014-11-17). "Jan 19 fixed for hearing in Shitta land case". Vanguard News. Retrieved 2023-03-12.