Jump to content

Mr eazi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọjọ́ kankàn-dín-lógún, oṣù Agẹmọ, ọdún 1991 ní wọn bí Oluwatosin Ajibade[1] tí orúkọ ìnàgijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Mr Eazi. Olórin ilẹ̀ Nàìjíríà ni, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ òǹkọrin àti oníṣòwò. Ó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí ó dá orin Banku , iyẹn àpapọ̀ ohùn orin Ghana àti ilè Nàìjíríà [2]. Mr Eazi kó lọ sí Kumasi, ní orílẹ-èdè Ghana ní ọdún 2008, ó sì wọlé sí KNUST níbi tí o tí ń gba àwọn òsèré láti wá ṣeré ní ìnáwó iléèwé..[3]

Ó fi ìfẹ́ hàn sí orin kíkọ nígbà tí ó ṣe orin rẹ̀ "My Life",

Àwọn ìtọ́kasí.

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Solanke, Abiola (17 November 2016). "'I'll be working with Wizkid on "Skin tight" remix' singer says on Beats 1". Pulse. Archived from the original on 1 April 2019. Retrieved 16 August 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Kenner, Rob (13 February 2017). "Introducing Mr Eazi, the OVO and Wizkid Favorite Bringing Afrobeats to the Masses". Complex. Archived from the original on 15 April 2017. https://web.archive.org/web/20170415011656/http://www.complex.com/music/2017/02/mr-eazi-talks-wizkid-and-ovo-connections-and-afrobeats. Retrieved 22 March 2017. 
  3. Phiona Okumu (26 April 2017). "Mr Eazi Is West Africa's Newest Superstar". The Fader. http://www.thefader.com/2017/04/26/mr-eazi-interview-accra-to-lagos-money. Retrieved 29 April 2017.