Jump to content

Nagmeldin Ali Abubakr

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Nagmeldin Ali Abubakr (tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejì, ọdún 1986) jẹ́ eléré Sudan tó sábà máa ń kópa nínú àwọn eré mítà irinwó. A bí i ní Khartoum.

Àkókò tí ó dára jùlọ ti ara rẹ̀ jẹ́ ẹ̀rin lé ní ogójì lé díẹ̀ (44.93) àáyá, tí ó ṣàṣèyọrí ní Oṣù Kẹrin ọdún 2005 ní Mecca.

Ali kópa nínú ìdíje 400 mítà ní àwọn eré Òlímpíìkì ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn ọdún 2008 ní Beijing tí ó kùnà láti lọ sí ìparí eré náà.

Ó ń gbé ní Nyala, Gúúsù Darfur, ó sì jẹ́ ọ̀gágun nínú ẹgbẹ́ ọmọ ogun Sudan. Ìdílé rẹ̀ jẹ́ ti ẹ̀yà Zaghawa (Beri).[1]

Àwọn Àṣeyọrí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Representing
2003 World Youth Championships Sherbrooke, Canada 1st 400 m 44.93
2nd 4 × 400 m relay 3:08.81
World Championships Helsinki, Finland 15th (sf) 400 m 46.67
2007 All-Africa Games Algiers, Algeria 6th 400 m 46.29
7th 4 × 400 m relay 3:09.37
Pan Arab Games Cairo, Egypt 5th 200 m 21.27
1st 400 m 46.16
2nd 4 × 400 m relay 3:06.52 (NR)
2008 African Championships Addis Ababa, Ethiopia 1st 400 m 45.64
Olympic Games Beijing, China 50th (h) 400 m 47.12
2009 World Championships Berlin, Germany 36th (h) 400 m 46.48

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Darfur athletes train as Olympic row rages", Reuters, April 15, 2008