Ìbínibí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Nation)
Jump to navigation Jump to search

Ìbínibí je agbajo awon eniyan ti won ni ibapinpo gidi tabi tikosi itan kanna, asa, ede tabi orisun.[1] Idagbasoke ati isegbejadeimo ibínibí je bibatan gbagbagba mo idagbasoke awon isejoba tonile-ese elero ayeodeoni ati awon egbe imurinkankan aseonibinibi ni Europe ni awon odunrun 18jo ati 19sa,[2] botilejepe awon asonibinibi n fa ibinibi lo si ijohun lori ila itan jijapo.[3]
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nation", The New Oxford American Dictionary, Second Edn., Erin McKean (editor), 2051 pages, May 2005, Oxford University Press, ISBN 0-19-517077-6.
  2. Dictionary of the History of Ideas: s.v. "Nationalism"
  3. Fun apere imukede aigbarale ti awon ara Irelandi fa akitiyan awon ara Irelandi si ijobalelori awon ara Geesi de bi odun 700.