National Agency for Food And Drug Administration And Control (NAFDAC)
Ìrísí
National Agency for Food And Drug Administration And Control (NAFDAC) | |
---|---|
Agency overview | |
Formed | Àdàkọ:Startdate |
Jurisdiction | Nigeria |
Headquarters | Abuja, FCT, Nigeria 9°03′19″N 7°27′23″E / 9.055206°N 7.456496°E |
Agency executive | Mojisola Adeyeye, Director General |
Website | |
http://www.nafdac.gov.ng/ |
National Agency for Food and Drug Administration and Control (NAFDAC) jẹ́ àjọ tí ó ń rí sí ìṣàkóso ipò Oògùn, óńjẹ ìbílẹ̀ àti tókè Òkun, ohun èlò ìṣaralóge (costmetics), ohun èlò Ilé-ìwòsàn, omi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àjọ Nafdac yí wà lábẹ́ àṣẹ àti àkóso Federal Ministry of Health ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2][3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Understanding what NAFDAC does". LawPàdí. 2019-06-26. Retrieved 2019-12-22.
- ↑ "Registered Products – NAFDAC". NAFDAC – National Agency for Food & Drug Administration & Control. Retrieved 2019-12-22.
- ↑ "NAFDAC". NEPC. 2018-07-10. Retrieved 2019-12-22.