Jump to content

National Trade Union Federation

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

National Trade Union Federation jẹ́ àgbájọpọ̀ àwọn àjọ ayédáadé àti àjà fẹ́tọ̀ọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan.[1] Ó fẹ́ẹ̀ jẹ́ pé gbogbo orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan ni ó ní ajọ̀ yìí káàkiri ní orílẹ̀-èdè wọn, tí wọ́n sì ní ilé-iṣẹ́ àjọ yìí káàkiri. Àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ni ju ilé-isé kan lọ fún àjọ yìí. Làwọn àgbègbè mìíràn, pàápàá jù lọ àwọn orílẹ̀-èdè apá àríwá Europe, wọ́n ni ilé-isé àjọ yìí fún àwọn oníṣẹ́-ọwọ́, bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n tún ní i fún àwọn alákọ̀wé òṣìṣẹ́.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]