Ọrùn
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Neck)
Ọrùn | |
---|---|
Ọrùn ènìyàn | |
Latin | collum |
Dorlands/Elsevier | Ọrùn |
Ọrùn jé èyà ara tó so orí pò mó ara, ó le jé ní ènìyàn tàbí eranko. Orùn ní ó n gbé orí dúró, inú rè sì ni isan tí ó n mú orí yí si sotun-sosi wà.[1]
Orùn se idabobo fún apá kan òpá èyìn àti àwon nafu ara kòkan tí oun lo látorí orsí àwon èyà ara mír, orùn sì tún jé idabobo àti ònà fún àwon ohun èlò èjè tí oun lo sí orí àti èyi to ún padà sáyà.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- <"The Key Muscle for Your Neck Function". Verywell Health. 2012-08-30. Retrieved 2022-02-23.