Jump to content

Netsanet Achamo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Netsanet Achamo tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù December, ọdún 1987 jẹ́ eléré sísá ọ̀nà jínjìn ti orílẹ̀-èdè Ethiopia.[1]

Netsanet parí pẹ̀lú ipò kẹrin nínú ìdíje àwọn eléré ní ọdún 2006 ní 3000 metres. Achamo kópa nínú ìdíje àgbáyé ti eré-sísá nínú 300 metres ti Steeplechase ní ọdún 2007. Arábìnrin náà gba idẹ nínú eré gbogbo ilẹ̀ Afirica ti ọdún 2007 lórí 3000 metres ti steeplechase[2]. Achamo yege nínú ìdajì Olomouc Marathon ní ọdún 2011, Mumbai Marathon ti ọdún 2012 àti Hamburg Marathon ti ọdún 2012[3][4][5].

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Netsanet ACHAMO Profile
  2. All-African Games silver medallist Netsanet Achamo
  3. 2016 Hamburg Marathon
  4. Hamburg Marathon
  5. 2012 Mumbai Marathon and 2012 Hamburg Marathon