Ngozi Eucharia Uche

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ngozi Eucharia Uche
Personal information
OrúkọNgozi Eucharia Uche
Ọjọ́ ìbí18 Oṣù Kẹfà 1973 (1973-06-18) (ọmọ ọdún 50)
Ibi ọjọ́ibíMbaise, Nigeria
National team
Nigeria women's national football team
Teams managed
Nigeria women's national football team
† Appearances (Goals).

Ngozi Eucharia Uche jẹ ọkan lara agbabọọlu obinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 18, óṣu June ni ọdun 1973. Arabinrin naa jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti o si jẹ ólóri coach tẹlẹ ri fun team apapọ awọn obinrin lori bọọlu[1][2][3].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ngozi jẹ obinrin coach akọkọ fun super falcons. Ni ọdun 2010, agbabọọlu naa jẹ obinrin akọkọ to yege ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica[4][5].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.eurosport.com/football/eucharia-ngozi-uche_prs281738/person.shtml
  2. https://fbref.com/en/players/ccf9ad30/Ngozi-Uche
  3. https://peoplepill.com/people/uche-eucharia
  4. https://bestchoicesports.com.ng/the-many-firsts-of-uche-eucharia-in-super-falcons-30-years-and-counting/
  5. https://www.emc3nigeria.com/nigeria-wins-women-africa-cup-of-nation/