Nigerian Army
Ìrísí
Nigerian Army Ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà | |
---|---|
Fáìlì:Nigerian Army crest.gif Crest of the Nigerian Army | |
Ìdásílẹ̀ | 1960-present |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Irú | Army |
Headquarters | Abuja, Nigeria |
Motto | Victory is from God alone |
Àwọn apàṣẹ | |
Chief of Army Staff | Lieutenant general Ibrahim Attahiru [1] |
Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà (tàbíNigerian Army (NA)) jẹ́ ọ̀kan lára ilé-iṣẹ ológun orí ilẹ̀ ti ilé-iṣẹ́ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, ilé-iṣẹ́ nàá ní àwọn ọmọ ogun tí ó pọ̀ jùlọ , tí iye wọn tó 100,000.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtoka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ http://www.nigerian-army.org/index.php?option=com_content&task=view&id=63&Itemid=1&fontstyle=f-default
- ↑ IISS Military Balance 2007, p.287