Nike Art Gallery

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Nike Art Gallery jẹ́ orúkọ ibi ìṣàfihàn àwòrán kan ní ìlú Èkó àti ní ìlú Ọ̀ṣun tí arábìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Nike Davies-Okundaye dá sílẹ̀. Ilé ìṣàfihàn àwòrán yìí jẹ́ lára èyí tí ó tóbi jù lọ ní orílẹ̀-èdè West Africa. Iyàrá tó wà ní ilé-alájà gíga márùn-ún, tí ó sì fí àwọn àwòrán tó ń lọ bíi ẹgbààrin yangàn láti ọwọ́ àwọn ayàwòrán bíi Olóyè Josephine Oboh Macleods.[1][2][3][4][5]

Àwòrán Nike Art Gallery, Ní Abuja
Àwòrán Nike Art Gallery, Ní Èkó

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Onnaedo Okafor (October 15, 2014). "Lagos' Best Kept Secret". The Pulse. http://pulse.ng/celebrities/nike-art-gallery-lagos-best-kept-secret-id3200875.html. Retrieved August 26, 2015. 
  2. "The Lagos You Don’t See: The amazing Nike Art Gallery in Lekki". Naija Treks. Retrieved August 26, 2015. 
  3. Olamide Babatunde. "Euphoric with culture: Nike Art Gallery celebrates African heritage". Sun News. http://sunnewsonline.com/new/euphoric-with-culture-nike-art-gallery-celebrates-african-heritage/. Retrieved August 26, 2015. 
  4. Christie Uzebu. "Nike Art Gallery: Promoting Nigeria's Arts and Culture". CP Africa. Archived from the original on August 26, 2015. https://web.archive.org/web/20150826224815/http://www.cp-africa.com/2015/08/12/nike-art-gallery-promoting-nigerias-arts-and-culture/. Retrieved August 26, 2015. 
  5. "chief Josephine oboh macleod art creator connoisseur politician activist/". vanguardngr.com. 2021-05-01.