Nous aurons toute la mort pour dormir
Ìrísí
Nous aurons toute la mort pour dormir | |
---|---|
Adarí | Med Hondo |
Olùgbékalẹ̀ | Les Films du Soleil Ô |
Òǹkọ̀wé | Med Hondo |
Ìyàwòrán sinimá | Jean Monsigny |
Olóòtú | Youcef Tobni Hamid Djellouli |
Olùpín | Les Films du Soleil Ô |
Déètì àgbéjáde | 23 March 1977 (France) |
Àkókò | 160 min. |
Orílẹ̀-èdè | France Mauritania |
Èdè | French |
Nous aurons toute la mort tú dormir, jẹ́ eré ti ọdún 1977 lórílẹ̀-èdè Mauritáníà, èyí tí Med Hondo ṣé adarí rẹ̀.[1][2]
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe fíìmù náà láti 25 Oṣù Kejìlá Ọdún 1975 títí di 5 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1976.[3] Fíìmù náà dá lóri akitiyan àwọn ẹgbẹ́ Polisario Front láti bọ́ nínu oko-ẹrú ọwọ́ orílẹ̀-èdè Spain.[4] Fíìmù náà jẹ́ wíwò níbi ayẹyẹ Berlin International Film Festival ti ọdún 1977.[5][6]