Nozizwe Madlana-Routledge
Nozizwe Charlotte Madlala-Routledge (pronunciation: /nɔːziːzwɛ/ /ˈʃɑːlət//mɑːdθlæθlɑː/-/ˈraʊtlɛdʒ/) (abi ni ojo ookan diladota ninu osu kefa, odun 1952)je oloselu ara Guusu Afrika.ohun ni igbakeji agba tele fun asojare ni Guusu Afrika lati odun 1999 si osu kerin odun 2004,ohun si ni igbakeji agba fun Ilera lati osu kerin ni odun 2004 si osu kejo ni odun 2007. Aare Thabo Mbeki yoo kuro ni ojo kejo osu kejo ni odun 2007,leyin igba na ni o bojuto ipa re gegebi ara egbe awon asofin oduro fun African National Congress.
Ni ojo karun leloogun ninu osu kesan odi igbakeji agbọrọsọ ni National Assembly, osi sise ni agbara re titi ofi fiwesile kuro lara awon asofin ni osu kaarun odun 2009.Owa lara South African Communist Party lati odun 1984.
Madlala-Routledge gbajumo fun iranlowo ikojasi Arun Kogbogun AIDS ni Guusu Afrika,opolopo eniyan kaakiri mo pe o koo ikeyin si ijoba nipa lile ajakale naa.Otun je alatako lilo ogun miran fun itoju arun kogbogun dipo ogun to peye ati ona ati koja si.
Laipe,Madlala-Routledge se eleto agba Inyathelo fun igba ranpe: Ile eko ilosiwaju ni Guusu Afrika titi osu keta ni odun 2015 nigba to fisesile nitori awon isoro to waye larin awon igbimo