Jump to content

Ice Cube

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti O'Shea Jackson)
Ice Cube
Cube, 2012
Cube, 2012
Background information
Orúkọ àbísọO'Shea Jackson
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiCube, Don Mega
Ọjọ́ìbí15 Oṣù Kẹfà 1969 (1969-06-15) (ọmọ ọdún 55)
Los Angeles, California[1]
Ìbẹ̀rẹ̀South Central Los Angeles, California, U.S.
Irú orinHip hop, gangsta rap, political hip hop
Occupation(s)Rapper, actor, film director, screenwriter
Years active1984–present
LabelsPriority (1987–1996)
Lench Mob (1994–present)
EMI (1987–present)
Associated actsN.W.A, C.I.A., Scarface, Da Lench Mob, Westside Connection, Public Enemy, WC and the Maad Circle, Snoop Dogg Boo-Yaa T.R.I.B.E.
Websiteicecube.com

O'Shea Jackson (ojoibi June 15, 1969), to gbajumo pelu oruko ori itage re Ice Cube, je rapper, osere, olukowe-ere, oludari filmu, ati atokun. O bere ise orin re gegebi ikan ninu awon omo egbe olorin hip-hop C.I.A. ati leyin re o di omo egbe olorin rap N.W.A. Leyin igba to fi N.W.A sile ni December 1989,[2] o bere ise idakorin to yorisirere, ati bi olukowe, oludari, osere ati atokun sinema. Bakanna, o ti se bi ikan ninu awon atokun awon ere ori telifisan Showtime tounje Barbershop ati ti ori telifisan TBS tounje Are We There Yet?, awon mejeeji ti won da lori awon filmu to se bi osere.



  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Allmusic
  2. N.W.A. at Discogs.com