October rain

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

October Rain jẹ́ ayẹyẹ tó ma ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún. Ó jẹ́ àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́ ọnà Ilẹ̀ Nàjíríà, ìyẹn 'Society of Nigerian Artits' (SAN). Àsìkò ayẹyẹ àjọ̀dún yìí ni ọ̀pọ̀ nínú àwọn oníṣẹ́ ọnà náà ma ń ṣàfihàn iṣẹ́ ọnà àtinúdá wọn fáráyé rí, àti láti lè ṣègbélárugẹ fún àwọn ènìyàn tí ó ti tiraka láti kópa nínú ìdàgbà-sókè orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Dailytimes; Dailytimes (2018-10-13). "SNA Lagos chapter marks "October Rain"". Daily Times Nigeria. Retrieved 2018-11-17.