Jump to content

Ofada rice

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Iresi Ofada (oke apa ọtun) pẹlu ọgede didin ati ẹran malu
Iresi Ofada

Ofada rice tàbí iresi Ofada jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ounjẹ Yoruba. Ó jẹ́ orúkọ tí wón fún iresi ti wọ́n gbìn ní ìlú Ofada ni agbègbè Obafemi Owode Ìpínlẹ̀ Ogun. Kò kín se ìlú Ofada nìkan ni wọ́n ti ń gbin. Wọ́n ma ń gbin ni gúúsù apá ìwọ oòrùn Nàìjíríà sugbon orúkọ ìlú náà ni wọn fun.[1][2][3] Wọ́n fi iresi Ofada se ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oúnjẹ yìí sì jẹ́ asepo. Àwọn nkan míràn ti wón fi kún àwọn asepo yìí kí se láti Nàìjíríà tàbí Áfríkà. Wọn ń gbin iresi Ofada ní ilè olómí.[4]

  1. "Have you had a taste of Ofada rice?". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-16. Retrieved 2022-04-07. 
  2. "Ofada rice originated from my domain – Olu of Igbein". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-07. Retrieved 2022-06-01. 
  3. "Have you had a taste of Ofada rice?". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-16. Retrieved 2022-06-01. 
  4. Udevi, Obiamaka Angela (2019-03-18). "Origin of Nigerian Foods: Ofada Rice • Connect Nigeria". Connect Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-07.