Oko Ẹru ni Etikun ti Barbary

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The slave market of Algiers in the early 17th century.

Oko Ẹru ni Etikun ti Barbary (Owo Oko Ẹru ni Etikun Barbary) jẹ iṣẹ labira ti kin ṣè ọfẹ to waye larin century ti mẹrin dinlogun ati meji dinlogun ni agbegbe Etikun Barbary ni apa ariwa ti ilẹ Afrika.

Ija ogun ti Barbary[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gẹgẹbi iwadi Robert Davis, ọpọlọpọ awọn ara ilẹ Europe ni awọn ole abẹ omi ti Barbary ko ti wọn si ta wọn lẹru ni ariwa ilẹ Africa ati Afin ti Ottoman larin century ti mẹrin dinlogun ati ọkan dinlogun.

Lati iṣalẹ ti Etikun ti Barbary, ariwa ilẹ Afrika, awọn ole abẹ omi ja ọkọ oju omi gba eyi to ṣe irin ajo lọ si Mediterranean, ariwa ati iwọ oorun etikun ti ilẹ Africa ti wọn si ko awọm ero bẹ lẹru.

From at least 1500, the Awọn ole abẹ omi yi tun kogun ja awọn ilu etido to wa ni ilẹ Italy, Spain, France, England, Netherlands ati Iceland ti wọn si ko óbinrin, ọkunrin ati ọmọde lẹru. Larin ọdun 1609 ati 1616, England pofo ọpọlọpọ ọkọ oju omi si olè abẹ̀ ọmi ti Barbary lọwọ.

Ọrọ nipa Oko Ẹru[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ninu afiwe ọrọ nipa ẹru ti ariwa ilẹ America ati ọrọ nipa ẹru ilẹ Caribbean ni ede gẹẹsi ni awọn ẹru alawọ funfun ti ilẹ America ati British kọ. Ọrọ yii lo yatọ si iṣọkam ti awọn óniṣowo ẹru ti ẹlẹsin musulumi, ṣugbọn ọrọ awọn ẹru ti Africa-America maa npe awọn óniṣowo ẹru ni ẹlẹsin christaini.

Ọrọ to da lori ominira to jẹ oun iwuri lati ilẹ America.Nigba to jẹ̀ pe awọn ọrọ yi wọnu ara wọn, awọn onimimọ gbagbọ pe pupọ ninu awọn ọrọ yii ju ti awọn ti wọn ko lẹru lọ. Awọn obinrin ti wọn ko lẹru ni wọn lo ni Gothic fiction to tumọ si imọlẹ imonira ti awọn ara ti oun wo gbagbọ.

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]