Olatunde Farombi
Ìrísí
Olatunde Farombi jé ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ Biochemistry àti Molecular toxicology. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Royal Society of Chemistry (FRSC) UK, àti Nigerian Academy of Science. Ó sì tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ African Academy of Sciences at Academy of Toxicological Sciences. Ó gboyè ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ Biochemistry láti ilé ẹ̀kọ́ gíga, ìyẹn Yunifásítì ìlú Ìbàdàn.[1]
Ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn onímọ̀ Toxicology ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "The AAS". Farombi Ebenezer. Archived from the original on 2023-01-26. Retrieved 2023-02-03.
- ↑ Osinusi, Femi (2021-03-19). "Gureje, Farombi, others make list of top world scientists". Tribune Online. Retrieved 2023-02-03.