Olayinka Koso-Thomas
Ìrísí
Olayinka Koso-Thomas | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1937 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà, Sierra Leone |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Sierra Leone |
Olayinka Koso-Thomas (tí a bí ní ọdún 1937) jẹ́ Dókítà alábẹ́rẹ́ tí a bí ní Nàìjíríà ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè Sierra Leone.[1] Wọ́n mọ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè fún ipa rẹ̀ láti dá sí ṣẹ abẹ ojú ara àwọn ọmọbìnrin jòjòló dúró. Ní ọdún 1998, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Prince of Asturias Award fún iṣẹ́ rẹ̀.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ White, E. Frances (1989). "Review of The Circumcision of Women: A Strategy for Eradication". The International Journal of African Historical Studies 22 (2): 366–368. doi:10.2307/220074. ISSN 0361-7882. https://www.jstor.org/stable/220074.
- ↑ "Prince of Asturias Award profile". Archived from the original on 2008-10-07. Retrieved 2023-04-07.