Omi Ọ̀sà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Omi Ọ̀sà tàbí Omi Iró jẹ́ omi alagba-lúgbú tí ó dúdú lójú tàbí ní ìrísí. Omi òsà jẹ́ omi tí ẹnìkan kò mọ ibi tí ó ti ṣàn tàbí ṣẹ̀ wá. Ko Kò fẹ́rẹ̀ síbi tí omi yí kò ṣán dé lórílẹ̀ àgbáyé. Oríṣiríṣi ẹja àti ẹran omi lò ń gbé nínú omi náà.[1][2][3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Omi Osa - The Mystic River". Steemit. 2018-06-02. Retrieved 2019-12-15. 
  2. "Olokun, Osaara: The making of Atlantic Ocean, Lagos Lagoon". The Sun Nigeria. 2018-05-17. Retrieved 2019-12-15. 
  3. "Chapter III: Minor Gods.". Internet Sacred Text Archive Home. Retrieved 2019-12-15.