Jump to content

Omolade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Ọmọladé jẹ orúkọ ọmọ Naijiria. O tumo si" Ọmọ ni ade. " [1] nígbà mìíràn won man pe ni Moladé tabi Ladé.

Awọn eniyan olokiki pẹlu orukọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ajibade Omolade (ojoibi 1984), agbaboolu Naijiria
  • Akeem Omolade (ojoibi 1983), agbaboolu Naijiria
  • Omolade Akinremi (ojoibi 1974), omo Naijiria
  • Abisola <b id="mwFw">Omolade</b> (ojoibi 1974), oludari ise ona Naijiria, onise isejade, ayaba ẹwa ati oniṣiro tẹlẹ. 
  1. https://www.yorubaname.com/entries/omolade