Oníṣe:Bibiire1

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Orúkọ mi ni Kezia Alabija, tí orúkọ oniṣẹ́ mi ń jẹ́ Bíbíire. Mo jẹ́ olùkọ́ nílé ẹ̀kọ́ girama. Inú mi ma ń dùn láti ma ṣe àfikún sí ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia.