Oníṣe:Crystalpenedu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Orin Kèǹgbè ni ìlú Ìlọrin ni ìpínlè Kwara

Orin kèǹgbè jẹ́ ọ̀kan lára àṣà àti ìṣe ìlú Ìlọrin ni ayé àtijọ́ . Ọkàn lára ìṣe ọna si ni orin kèǹgbè jẹ́ . Kì í ṣe ìlú Ìlọrin nìkan ni ó máa ń kọ orin kèǹgbè ni ayé òde òní ṣùgbọ́n ó tọ́ kí á fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ìlú Ìlọrin ni ó ní orin kèǹgbè kíkọ .