Oníṣe:Oluwatosin552
Ìrísí
Orúkọ Oṣù Nílẹ̀ Yorùb
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- GẸ̀Ẹ́SÌ YORÙBÁ
- January ṣẹẹrẹ
- February Èrèlé
- March Erénà
- April Igbe
- May Èbìbí
- June Okúdù
- July Agẹmọ
- August. Ògún
- September Ọ̀wẹ̀wẹ̀
- October Ọ̀wàrà
- November Béélú
- December Ọpẹ́[1]