Oníṣe:T Cells/Adanwo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Forúkọ wọlé tàbí kí o ṣẹ̀dá orúkọ lóri Wikipedia (O ṣẹ̀dá orúkọ ní èyíkéyí àwọn èdè Wikipedia, pàápàá jùlọ èdè abínibí rẹ. O lè rí gbogbo àwọn èdè tí Wikipedia wà ni ibí.


Ṣe àwárí àyọkà tí ó fẹ́ fi àwòrán túnṣe. Wọlé síbí kí o ṣàwárí àkọ́lé àyọkà. O tún lè lo ojú ewé àrìnàko fi ṣàwárí àyọkà.


Láti ṣàyàn àwòrán tí ó bá àyọkà mu wọlé síbí, kí o sì ṣàwárí rẹ̀ níbí kí o sì ri dájú wípé orúkọ àwòrán tí o fẹ́ lò ṣe rẹ́gí. O sì lè ṣe àwárí nínu ìsọ̀rí. Fún àpẹẹrẹ c:Category:Wiki Loves Africa


On the article page, click Edit and insert the image chosen in Step 3, including a brief caption in the WP's language. Check the display position in "Preview" and make any necessary changes. Then click on "Publish changes."

Lórí àyọkà, tẹ ṣàtúnṣe kí o sì fi àwòran tí a sàlàyé rẹ̀ lókè yìí si, pẹ̀lú àpèjúwe ráńpẹ́. Ṣe àyẹ̀wo rẹ kí o tó ṣatẹ̀jáde rẹ̀ ní 'Àyẹ̀wò' kí o ṣàtúnṣe tí ó bá yẹ. Kí o tẹ Ṣàtẹ̀jáde ojú ewé.

Include the hashtag #WPWP in the edit summary of all articles improved with images.


Fi àmì ìdánimọ̀ #WPWPìṣoníṣókí gbogbo àwọn àyọkà tí o fi àwòran ṣàtúnṣe rẹ̀


You may also participate by creating new articles for quality photos.

O tún lè kópa látàri kíkọ àyọkà tuntun pẹ̀lu àwọ̀n tí ó dára.

Àwọn òfin ìdíje[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Òfin àkọ́kọ́ : Àwọn tí ó ń kópa gbọ́dọ̀ fi àmì ìdánimọ̀ #WPWPìṣọníṣókí àtúnṣe gbogbo àyọkà tí o fi àwòrán túnṣe. Fún àpẹẹrẹ "+image #WPWP"
  • Òfin kejì:Àwòrán yìí gbọ́dọ̀ bá àyọkà
  • Òfin kẹta : Àpèjúwe ráńpẹ yìí gbọ́dọ̀ ní ṣe pẹ̀lú àyọkà, ọ sì gbọdọ yé àwọn tí ó ń wò
  • Òfin kẹrin: Àwọn tí ó ń kópa gbọ́dọ̀ fi gbọ́dọ̀ fi orúkọ sílẹ̀ ní èyíkéyí àwọn àgbékàlẹ̀ ètò Wikimedia
  • Òfin karún: Àwọn tí ó ń kópa gbọ́dọ̀ fi àwòrán tún ojú ewé ṣe nígbà tí ìdíje yìí bá ń lọ lọ́wọ́ láti ọjọ́ àkọ́kọ́ oṣù kéje sí ìparí oṣù kẹjọ


Àkókò ìdíje[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíje yìí jẹ̣́ ọlọ́dọọdún, tí ó máa bẹ̀rẹ̀ ní oṣù keje ọdún 2020. À ó ṣe ìkéde ọjọ́ àti àkọ́lé ti ọdún yìí

This contest is annual, beginning in July 2020. Dates and themes to be announced.

Àwọn Àyọkà Wikipedia ń fẹ́ Àwòrán









Bí o ṣelè kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wikipedia Pages Wanting Photos (WPWP) jẹ́ ìdíje ti ọlọ́dọọdun tí àwọn olọ́òtú Wikipedia káàkiri àgbáyé maá ń fí àwòrán tún ojú ewé àyọkà ṣe ní gbogbo èdè Wikipedia pátá. À ń ṣe èyí láti ṣe ìmúlò àwọn àwòrán tí à gbà látàri oríṣiríṣi ètò àtí àwọn ìdíjé tí ó n gba àwọn wọlé fún lílò ní àyọkà Wikipedia. Àwòrán wíwò maá fani mọ́ra jú kíkà lọ, tí ó sì maá n jẹ́ kí òye àyọka yéni yékéyéké.


Thousands of images have been donated and contributed to Wikipedia Commons via various advocacy programs, photowalks, and contests including international photography contests such as Wiki Loves Monuments, Wiki Loves Africa, Wiki Loves Earth, Wiki Loves Folklore, etc. Yet relatively few of these photos have been used on Wikipedia articles. Today, the Wikimedia Commons hosts millions of photo images but only a tiny portion of these have been used on Wikipedia article pages. This is a huge gap that this project aims at bridging.

Ẹgbẹgbẹ̀rú àwọn àwòran ní wọ́n ti gbé sí Wikimedia Commons látàri oríṣiríṣi ètò àtí àwọn ìdíjé bíi Wiki Loves Monuments, Wiki Loves Africa, Wiki Loves Earth, Wiki Loves Folklore tí ó sì jẹ́ wípé díẹ̀ nínú àwòrán wọ̀yí ní wọ́n ń ò fi tún àyọkà Wikipedia ṣe. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọnù àwòrán ni ó wà ní Wikimedia Commons lónìí ṣùgbọ́ bíńti ni wọ́n ti lò tún ojú ewé àyọkà ṣe.


is an annual contest where Wikipedians across Wikipedia language projects and communities add photos to Wikipedia articles lacking images. This is to promote the use of digital media files collected from various WP photography contests, photowalks organized by the Wikimedia community, on Wikipedia article pages. Photos help to grasp the reader's attention better than a wall of text, illustrate content, and make the article more instructive and engaging for readers.