Onyekachi Apam
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Onyekachi Apam | ||
Ọjọ́ ìbí | 30 Oṣù Kejìlá 1986 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Aba, Nigeria | ||
Ìga | 1.77 m (5 ft 10 in) | ||
Playing position | Defender | ||
Youth career | |||
–2003 | Pepsi Football Academy | ||
2004–2005 | Enugu Rangers | ||
2005–2006 | Nice | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2006–2010 | Nice | 105 | (1) |
2010–2014 | Rennes | 23 | (0) |
2014 | Seattle Sounders FC | 0 | (0) |
National team | |||
2005 | Nigeria U20 | 6 | (0) |
2008 | Nigeria U23 | 5 | (0) |
2007–2010 | Nigeria | 14 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Onyekachi Apam (tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kejìlá, ọdún 1986 ní Aba) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ Nàìjíríà ti tẹ́lẹ̀ tí ó fẹ̀yìntì ní ọdún 2014 lẹ́yìn tí ó farapa nígbà tí ó ńṣiré fún Seattle Sounders FC.[1] Ó ṣe aṣojú Nàìjíríà ní ọdún 2008 Summer Olympics ní Ìlú Beijing gẹ́gẹ́ bí apá kan ti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn ọkùnrin.[2]
Iṣẹ́ Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2005, Apam gbìyànjú fún OGC Nice, nibiti ó ti f'ọwọ́ sí nígbà náà. Ó ṣe àwọn ìfarahàn 105 àti pàápàá fàágùn àdéhùn rẹ̀ láti parí ní ọdún 2013 tó yẹ kó jẹ́ ọdún 2012 ṣáájú kí ó tó lọ sí Stade Rennes ni ọdún 2010.[3][4]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Mabuka, Dennis (2021-07-03). "Lesley Ugochukwu: Nigeria target signs contract extension at Rennes". GOAL. Retrieved 2021-07-21.
- ↑ Azikiwe, Ifeoha. Nigeria Echoes of a Century - Volume Two 1999-2014. p. 357. https://books.google.com/books?id=mAahpzY-p78C&pg=PA357.
- ↑ "Sounders FC Signs Onyekachi Apam". Sounders FC. 2014-09-19. Retrieved 2021-07-21.
- ↑ "Nice's Nigerian Apam Extends Contract". GOAL.com. 2008-10-21. Retrieved 2021-07-21.