Orúkọ àmútọ̀runwá
Àwọn àgbè bọ̀ wọ́n ní ilé láàárín wo, àwọn yorùbá ni a sọ ọmọ ni sódé ó lọ sájò òde aṣọ ọmọ ni sóbọ̀, ó lọ sájò ó bọ̀ a sọ ọmọ ni sórìnlọ ó lọ sájò kò padà wálé taa ni kò mọ̀ pé ilé ni ọmọ tí mú orúkọ anù lọ sí òde, ìdí rèé tí àwọn yorùbá fi mú ọ̀rọ̀ orúkọ ni pàtàkì ọkàn lára àwọn ọ̀nà tí àwọn yorùbá pín ìsòrí orúkọ sí ní orúkọ àmútọ̀runwá,
Yoruba ni, 'Idálň ni işè lú, Egùngún ni i gb'owó-ode Osogbo', aşa awon yà Yoruba miran wa ti ó ję pe eyi ti a gbà pe okunrin ni a fi npè, tako t'abo ni nje ni ibomiran, fun apeere, oruko bi Ige ati Talabi. Ni ilę ljebu ęrú ni ó nję Ojo, ati omo okunrin ati obinrin ti ó ba ti gbe ibi k'órùn wale aiye, Aina ni oruko ámútórunwá rè ti nwọn yio s
Ìwọ̀nyí ni díẹ̀ nínú orúkọ àmútorunwá
Taiwo
Kẹ́hìndé
Ìdòwú
Ìdògbé
Àlàbá
Ẹ̀ta òkò
Ọla
Ọ̀tunla
Òróyè
Ìgè
Ọmọ pẹ́,
Òjó
Àìná
Àjàyí
Dàda
Abọ́sẹ̀dé
Abíọ́nà
Babárìndé
Abíiná
Babátúndé
Yérímisá