Owó Ẹyọ
Ìrísí
Owó Ẹyọ jẹ́ ohun alùmọ́nì tí wón ń lò láyé àtijó gẹ́gẹ́ bí owó láti fi ṣe káràkátà láwùjo Yorùbá àti ilẹ̀ Áfríkà lápapò. Láwùjọ Yorùbá, a máa ń rí owó ẹyọ gẹ́gẹ́ bí àmín ọlà tàbí ajé. Àwọn mìíràn a máa lò ó gẹ́gẹ́ bí ẹgbà-ọrùn tàbí ẹgbà-ọwọ́ láti fi ṣẹṣọ̀ọ́.
A máa ń fi ṣe ẹ̀ṣọ́. Àwọn babaláwo á tún máa lò ó bí ọ̀pẹ̀lẹ̀ fún ifá dídá. [1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Esu Obara Owo Eyo". SpiritualTools.org. 2013-10-25. Retrieved 2019-10-14.
- ↑ "Cowrie Shells - Owo Eyo". Yoruba Imports. Retrieved 2019-10-14.