Oyeleye
Ìrísí
Oyèlẹ́yẹ jẹ orúkọ ọmọ Yorùbá ni orile-ede Nàìjíríà tí wọ́n ń fún ọmọ ọkùnrin. O jẹ orukọ akọ pẹlu orisun orúkọ Yoruba, eyiti o tumọ si " òye le fúnni ni iyì"
Awọn eniyan olokiki pẹlu orukọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Oyeleye Oyediran, Onimo ijinle sayensi ati oselu Naijiria
- Olateju Oyeleye (1924–2013), onisowo Naijiria
- Oluwa Femi Oyeleye (ọjọ́ìbí 1994), afẹṣẹja Naijiria