Jump to content

Pọ́nna

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pọ́nna
Àwòrán aibikita

'Ìkọ kedere'Pọ́nna jẹ́ ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn kan ṣoṣo tí ó ní ìtumọ̀ tó ju ẹyọ kan lọ. Ó jẹ́ ọ̀rọ̀ tí ìtumọ̀ rẹ̀ kò dá geere. Àbùdá kan gbòógì tí ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn Pọ́nna máa ń ní ni àì ní ìtumọ̀ kan pàtó. Ó jẹ́ ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn tí ìtumọ̀ rẹ̀ kò dúró sójú kan. Bí àpeere, "Ẹ̀wà"; èyí lè túnmọ sí ohun tí ó dára, bákan náà, ó tún túnmọ sí ẹ̀wà (beans) tí a máa ń jẹ. Èyí tó jásí wípé Ṣadé lẹ́wà (Sade is Beautiful) yàtọ̀ sí Ṣadé lẹ́wà (Sade has Beans) tàbí Sade ni ẹ́wà (Sade is the beauty).

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]