Jump to content

Peju Ogunmola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Peju Ogunmola
Ọmọ orílẹ̀-èdèNaijiria
Iṣẹ́òṣèrébìnrin . oǹkọ̀tàn . olóòtú
Olólùfẹ́Sunday Ọmọbọ́láńlé
Parent(s)
  • Kola Ògúnmọ́lá (father)

Peju Ogunmola tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́ta jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, oǹkọ̀tàn, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ ni Kọ́lá Ògúnmọ́lá, gbajúgbajà òṣèré tíátà tí ó ti di olóògbé. Ọkọ rẹ̀ ní òṣèré aláwàdà sinimá àgbéléwò, Sunday Ọmọbọ́láńlé, tí gbó ènìyàn mọ̀ sí Papi Luwe . Òun ló dípò ìyá fún Súnkànmí Ọmọbọ́láńlé, tí ó jẹ́ ọmọ ọkọ rẹ̀ àti òṣèré sinimá àgbéléwò bákan náà.[1] [2][3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]