Peter Abelard

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Pierre Abélard
"Abaelardus and Heloïse surprised by Master Fulbert", by Romanticist painter Jean Vignaud (1819)
Orúkọ Pierre Abélard
Ìbí 1079
Aláìsí 21 April 1142
Ìgbà Medieval Philosophy
Agbègbè Western Philosophers
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Scholasticism
Ìjẹlógún gangan Metaphysics, Logic, Philosophy of language, Theology
Àròwá pàtàkì Conceptualism, Scholasticism

Peter Abelard A bí i ní 1079. Ó kú ní 1142. Ó jé òkan lára àwon tí ó sèdá ohun tí a n pè ní scholastic theology. Olùkó ni ní Paris. Òpò akékòó ni ó máa n wá sódò rè. Òpin ìfé láàrin òun àti Heliose kò dára