Pierre Claver Maganga Moussavou
Ìrísí
Pierre Claver Maganga Moussavou | |
---|---|
5th Vice President of Gabon | |
In office 21 August 2017 – 21 May 2019 | |
Ààrẹ | Ali Bongo Ondimba |
Asíwájú | Didjob Divungi Di Ndinge (2009) |
Arọ́pò | Rose Christiane Raponda (2023) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kẹrin 1952 Mouila, French Equatorial Africa (present day Gabon) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Social Democratic Party |
Alma mater | National University of Gabon University of Rennes University of Paris |
Pierre Claver Maganga Moussavou (tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹrin ọdún 1952[1]) jẹ́ olóṣèlú ọmọ òrílẹ̀ ède Gabon, òun ni ó jẹ́ igbá kejì Ààrẹ Gabon láti ọdún 2017 sí 2019. Òun ni Ààrẹ Social Democratic Party.
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí sínú ìdílé Punu[2] ní Mouila, Maganga Moussavou kó nípa ìmọ̀ ìtàn ọrọ̀ ajé ní Yunifásítì orílẹ̀ ède Gabon, àti ní Yunifásítì Rennes. Ó kàwé gba àmì ẹyẹ Dókítà ní ilé ìwé Sorbonne ní orílẹ̀ èdè Fransi. Ó padà sí Gabon ní ọdún 1978.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ David E. Gardinier, Historical Dictionary of Gabon, p.466
- ↑ Franck Salin, "Pierre Claver Maganga Moussavou: "I am afraid for Gabon"", Afrik.com, 17 August 2009.
- ↑ "Election présidentielle au Gabon: Liste des candidats et leurs profils", Cameroun Link Àdàkọ:In lang