Place of Weeping

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 


Place of Weeping
AdaríDarrell Roodt
Olùgbékalẹ̀Anant Singh
Òǹkọ̀wéDarrell Roodt
Àwọn òṣèréJames Whyle
Gcina Mhlophe
Charles Comyn
Norman Coombes
Michelle du Toit
Kerneels Coertzen
Patrick Shai
OrinLloyd Ross
Ìyàwòrán sinimáPaul Witte
OlóòtúDavid Heitner
Ilé-iṣẹ́ fíìmùPlace of Weeping Productions
OlùpínAquarius TV (1993) (Greece) (TV)
Highlight Video (West Germany) (VHS)
New World Pictures (all media)
Déètì àgbéjádeỌjọ́ kaàrún Osù kejìlá Ọdún 1986
ÀkókòÌṣẹ́jú Méjìdínláàdọ́rùń
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
ÈdèAfrikaans
English
Zulu

Place of Weeping (ti tiata bi Afrika - Land der Hoffnung ), jẹ ere-orí ìtàgé ti orílẹ̀ èdè South Africa kan ti ó jáde ní ọdún 1986. Darrell Roodt ni ó ṣe olùdarí tí Anant Singh ṣe agbátẹrù fun Place of Weeping Productions. Àwọn ìràwọ̀ oṣèré James Whyle, Gcina Mhlophe àti Charles Comyn ni ó síwájú ipa eré oníse náà tí Norman Coombes, Michelle du Toit, Kerneels Coertzen àti Patrick Shai kópa àtìlẹyìn. Eré oníse náà ṣàpèjúwe ní kíkún nípa àwọn ẹgbẹ́ aláṣà ní South Africa àti bí South Africa ṣe wó látàrí iṣẹ́ ọwọ́ àwọn ará South Africa àti àsìkò ìjọba aninilára ti South Africa.

Èyí ni àkọ́kọ́ ìgbìyànjú nípa lílòdò sí ìja ẹlẹ́yàmẹyà ni orílẹ̀ ède South Africa. Eré oníse náà di àfihàn ní àkọ́kọ́ ní ọjọ́ kaàrún Oṣù kejìlá ọdún 1986. Eré oníse náà sì gba àwọn àtúnyẹ̀wò rere láti ọwọ́ àwọn alárìíwísí.

Oṣèré[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • James Whyle bi Philip Seago
  • Gcina Mhlophe bi Gracie
  • Charles Comyn bi Tokkie van Rensburg
  • Norman Coombes bi Baba Eagen
  • Michelle du Toit bi Maria van Rensburg
  • Kerneel Coertzen bi Agbẹjọro gbogbo eniyan
  • Patrick Shai bi Lucky
  • Ramolao Makhene bi Themba
  • Siphiwe Khumalo bi Joseph
  • Doreen Mazibuko bi Ọdọmọbìnrin
  • Thoko Ntshinga gege bi Opo Josefu
  • Elaine Proctor bi Akoroyin
  • Ian Steadman bi Dave, Olootu
  • Marcel van Heerden bi Kafe eni
  • Arms Seutcoau bi Faction Onija
  • Nandi Nyembe bi Iya Ọdọmọbìnrin
  • Ernest Ndlovu bi Eniyan pẹlu ibon
  • Nicky Rebelo bi Agbe 1
  • Sean Taylor bi Agbe 2

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]