Ewì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Poet)
Jump to navigation Jump to search

Ewì tabi Ewìkíkọ (Poetry lati Greek "ποίησις", poiesis, a "making") je iru ọnà litiraso ninu ibi ti ede ti n je lilo fun ewa re. Ewi se e ko fun ra re nikan tabi lapapo mo awon ona miran, fun apere drama elewi, orin oriki, liriki, tabi ewi akogun.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]