Rọ́bà Ìdáàbòbò
Ìrísí
Rọ́bà Ìdáàbòbò jẹ́ ohun èlò kan tí a lè fi dènà oyún àbadì, àìsàn, àrùn àti ìfara-káṣá tí ó lè ṣàkóbá fún àgọ́ ara ọkùnrin tàbí obìnrin nípasẹ̀ Ìbálòpọ̀ lásìkò tí a bá ń ní ìbòpọ̀ lọ́wọ́ tàbí lẹ́yì ìbálòpọ̀ ọ̀hún. (STI).[1] Tọkùnrin tobìnrin ni wọ́n ní rọ́bà ìdáàbòbò tiwọn. [2]
Àwọn ẹ̀rí máajẹ́mi nìṣó rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìwádi fi yéni wípé ó kéré tán ìdá méjì obìnrin ni wọ́n ma ń lóyún lọ́dún, nígbà tí ìdáná méjìdínlógún %18 l ó ma ń lóyún lọ́dún nígbà tí ọkọ wọn tàbí olólùfẹ́ wọn bá lo rọ́bà Ìdáàbòbò. [1] With typical use the rate of pregnancy is 18% per-year.[3] Lílo rọ́bà Ìdáàbòbò ti mú àdínkù bá kíkó àrùn àtọ̀sí, àrùn Eèdì àti àwọn mìíràn jọjọ. [4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Hatcher, Robert Anthony; M.D, Anita L. Nelson (2007) (in en). Contraceptive Technology. Ardent Media. pp. 297–311. ISBN 9781597080019. Archived from the original on 2017-09-18. https://web.archive.org/web/20170918185600/https://books.google.com/books?id=txh0LpjjhkoC&pg=PA297.
- ↑ WHO Model Formulary 2008. World Health Organization. 2009. p. 372. ISBN 9789241547659.
- ↑ Trussell, J (2007). "Contraceptive efficacy". Ardent Media. Archived from the original on 2013-11-12. https://web.archive.org/web/20131112130150/http://www.contraceptivetechnology.org/wp-content/uploads/2013/09/CTFailureTable.pdf. Retrieved 2011-03-13.
- ↑ Speroff, Leon; Darney, Philip D. (2011) (in en). A Clinical Guide for Contraception. Lippincott Williams & Wilkins. pp. 305–307. ISBN 9781608316106. Archived from the original on 2016-11-14. https://web.archive.org/web/20161114203840/https://books.google.com/books?id=f5XJtYkiJ0YC.
- ↑ Trussell, James (2011). "Contraceptive efficacy". In Hatcher, Robert A.; Trussell, James; Nelson, Anita L. et al.. Contraceptive technology (20th revised ed.). New York: Ardent Media. pp. 779–863. ISBN 978-1-59708-004-0. ISSN 0091-9721. OCLC 781956734. Archived from the original on 2013-11-12. http://www.contraceptivetechnology.org/wp-content/uploads/2013/09/CTFailureTable.pdf.