Rachael Muema
Ìrísí
Rachael Muema jẹ́ obìnrin agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ kenya tí a bí ní ọjọ́ kẹfà , oṣù kẹwàá ni ọdun 1999. Agbábọ́ọ̀lù náà ń gbá ipò àárín gbùngbùn fún Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Thika Queens FC[1][2][3][4]
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Rachael kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin ilẹ̀ Turkey ti ọdún 2020 níbi tí ó ti ṣojú agbábọ́ọ̀lù awọn obìnrin lórí pápá[5].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://nation.africa/kenya/sports/football/why-thika-queens-striker-rachael-muema-s-season-could-be-over-3816974
- ↑ https://allafrica.com/stories/202109210790.html
- ↑ https://www.flashscore.com.ng/player/muema-rachael/dhBWl7Zc/
- ↑ https://www.mozzartsport.co.ke/football/news/quick-fire-questions-with-rachael-muema/3830
- ↑ https://globalsportsarchive.com/people/soccer/rachael-muema/525343/