Jump to content

Rainat Komolafe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Rainat Komolafe jẹ Oludari ati Oludasilẹ BabiesEssence. O jẹ Oludari ile-iṣẹ meji: BabiesEssence, ti o n koni nipa bi a ṣe n gbaradi fun ọmọ tuntun jojolo ati Nikktun, ile itaja ohun elo amaradan ati bẹ bẹ lọ. Rainat jẹ ẹni ti o mu eto gbigbaradi fun ọmọ tuntun jojolo ni okunkundu ati ṣiṣeowo. BabiesEssence nikan ni ile-iṣe rẹ ti o wa ni Naijiria.[1]

  1. "Rainat Komolafe – Always ensure that your customers are satisfied – Business Mic". Business Mic – Podcast interviews with amazing Entrepreneurs. Retrieved 2018-08-25.