Jump to content

Raymond Ablack

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Raymond Ablack
Ablack in 2010
Ọjọ́ìbíRaymond Ablack
12 Oṣù Kọkànlá 1989 (1989-11-12) (ọmọ ọdún 35)
Toronto, Ontario, Canada
Ẹ̀kọ́Ryerson University
Iṣẹ́Actor, comedian
Ìgbà iṣẹ́2001–present

Raymond Ablack (tí wọ́n bí ní November 12, 1989) jẹ́ òṣèrékùnrin àti apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Canada. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2000, gẹ́gẹ́ bí i òṣèrémọdé, lóri ìtàgé, tó sì ṣe ẹ̀dá-ìtàn Young Simba nínú The Lion King ní Princess of Wales Theatre.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Where You've Seen The Ginny And Georgia Cast Before". CINEMABLEND. 2021-03-05. Retrieved 2021-05-06.