Rhythm 93.7 FM Port Harcourt
Ìrísí
Rhythm 93.7 FM jẹ́ rédíò ti iṣowo tí ó wà ní agbègbè Old GRA ti Port Harcourt, Ìpínlẹ̀ Rivers. Ilé iṣẹ́ rédíò yìí á máa ṣe àwọn ìkéde òde òní, wọ́n a máa gbé orin onírúurú síi bíi R&B, hip hop, pẹ̀lú orin-ijó lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan àti reggae . O jẹ ohun ini ati ẹ̀ka ìṣiṣẹ́ Silverbird Communications lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Silverbird Group àti pé ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-iṣẹ rédíò aládàáni tí ó lókìkí jùlọ ní ìhà gúúsù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ètò | Ago |
---|---|
Afternoon drive | Monday - Friday 2:00 PM - 4:00 PM |
Dance Party | Monday - Friday (ayafi Thursday) 7:30 PM - 10:00 PM |
Gospel Vibes | Sunday 8:00 AM - 10:00 AM |
Late Night caller | Tuesdays 10:00 PM - 12 AM |
Launch Box Oldies | Monday - Sunday 12:15 PM - 2:00 PM |
Mo Fire | Wednesdays 8:00 PM - 10:00 PM |
Morning Drive | Monday - Friday 6:00 AM - 10:00 AM |
Rap Culture | Saturday 6:30 PM - 8:00 PM |
Rhythm & Soul | Monday - Friday 10:00 AM - 12:00 PM |
Rhythm of the Night | Mondays 10:00 PM - 12:00 AM |
Showout Show | Saturday 2:00 PM - 4:00 PM |
Sunday at the Rhythm | Sunday 2:00 PM - 4:00 PM |
Shoutout show | Saturday 8:00 AM - 9:15 AM |
The TGIF Chart | Ọjọ Jimọ 9:00 Ọ̀sán - 10:00 Ọ̀sán |
Òṣìṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dísíkí Jokì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- DJ best
- DJ Spin
- DJ DoubleD
- DJ Golden
DJ Tan
Àwọn Olóòtú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Azubuike Wokocha
- Stephanie Obuzo
- Chikodi Nwosu
- Charlse Baridam
- Ben Wakama
Àwọn òṣìṣẹ́ orí afẹ́fẹ́ tẹ́lẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Andre Blaze, ṣiṣẹ́ Lọ́wọ́lọ́wọ́ ní The Virtuoso Company
- Ifeoma Iphie Aggrey-Fynn (ó kú 2015)
- Cleopatra Tawo, ó wà pẹ̀lú Planet FM 101.1 ni Uyo báyìí
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ òfin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù Kejìlá ọdún 2005, méjì nínú àwọn Olóòtú rédíò Klem Ofuokwu àti Cleopatra Tawo ni wọ́n mú tí wọ́n sì fẹ̀sùn kàn pé wọ́n sọ ìròyìn irọ́ nípa ìkùnà Afárá. Wọ́n fi wọ́n sẹ́wọ̀n fún ọ̀sẹ̀ méjì, lẹ́yìn náà ni wọ́n dá wọn sílẹ̀ lórí ẹ̀wọ̀n.
Wo eléyìí náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Orin ti Port Harcourt
- Àtòjọ àwọn ilé-iṣẹ́ rédíò ní Port Harcourt