Jump to content

Little Richard

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Richard Wayne Penniman)
Little Richard
Little Richard performing in March 2007
Little Richard performing in March 2007
Background information
Orúkọ àbísọRichard Wayne Penniman
Ọjọ́ìbí(1932-12-05)Oṣù Kejìlá 5, 1932
Macon, Georgia, U.S.
AláìsíMay 9, 2020(2020-05-09) (ọmọ ọdún 87)
Irú orin
Occupation(s)
  • Akọrin
  • akọ̀wé-orin
  • olórin
Instruments
  • Vocals
  • piano
Years active1947–2020
Labels
Associated acts

Richard Wayne Penniman (December 5, 1932 – May 9, 2020), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ Little Richard, jẹ́ akọrin, akọ̀wé-orin, àti olórin ará Amẹ́ríkà. Gẹ́gẹ́ bíi ènìyàn pàtàkì nínú orin alásìkí, àwọn iṣẹ́ orin Richard bẹ̀rẹ̀ ní ìgbà àrin àwọn ọdún 1950, nígbà tí agbára orin àti ìdán orin rẹ̀ ṣe ìpilẹ̀sẹ̀ fún orin rock and roll, nítoríẹ́ ni wọ́n ṣe pè é ní The Originator, The Emancipator, The Architect of Rock and Roll. A dáa mọ̀ fún bó ṣe ún tẹ pianó kíákíá àti fún ohùn rẹ̀ to da bíi pé ó há, orin Richard tún kópa nínú ìdásílẹ̀ àwon irú orin alásìkí míràn bíi soul àti funk. Ó nípa pàtàki lórí àwọn akọrin àti olórin káàkiri orísi irú orin láti rọ́ọ̀kìhip hop, bẹ́è sì ni orin rẹ̀ kópa lórí bí rhythm and blues ṣe dà lọ́jọ́ọwájú.

"Tutti Frutti" (1955), àti "Long Tall Sally" (1956) ni méjì nínú àwọn orin Richard tó gbajúmọ̀ jùlọ.