Jump to content

Robert Campbell (Colonist)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Robert Campbell (tí a bí ní 7 May 1829 – 19 January 1884) jẹ́ ọmọ bíbí orílè èdè Jamaican[1] tí ó fi ìgbà kan gbé ní orílè èdè United States kí ó tó lo sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ní àkókò ó kò ṣe lábẹ́ atèwéjáde kí ó tó kó ṣé láti di olùkọ́ ti Èdè Spéìn nígbà tí ó ri pé owó osù òun kéré nínú ìdàrúdàpò ọrọ ajé post-abolition Jamaica, Ó kó lo sí orílẹ̀ èdè Nicaragua and Panama kí ó tó wá tèdó sí orílẹ̀ èdè New York ní ọdún 1853. Ó sise bí atèwéjáde kí wọ́n tó gbà sí isẹ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ imọ science lẹ́yìn náà odi igbá kejì oga ilé ìwé Institute for Colored Youth ni Philadelphia Pennsylvania.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Shavit, David (1989). The United States in Africa – A Historical Dictionary. Westport, Connecticut: Greenwood Press. p. 37. ISBN 0-313-25887-2.