Rose Odika
Ìrísí
Rose Odika | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ìbàdàn |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 1988-till date |
Rose Odika jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Delta lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bí sí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.[1] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1988. Ó ti tó ọgbọ̀n (30) tí ó ti ń ṣiṣẹ́ sinimá-àgbéléwò lédè Yorùbá. Òun ni Gómìnà ẹgbẹ́ tíátà tí wọ́n ń pè ní Theater Arts and Motion Pictures Practitioners Association of Nigeria (TAMPAN) tí èka ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Rose Odika Biography - MyBioHub". MyBioHub. 2017-07-07. Retrieved 2020-02-07.
- ↑ "It took me 7 years after marriage to have a baby —Actress, Rose Odika » Kleiglight » Tribune Online". Tribune Online. 2020-01-11. Retrieved 2020-02-07.